Passt nicht? Macht nichts! Sie können Artikel bis zu 30 Tage zurückgeben
Mit einem Geschenkgutschein können Sie nichts falsch machen. Der Beschenkte kann sich im Tausch gegen einen Geschenkgutschein etwas aus unserem Sortiment aussuchen.
A bi Adeola Oreoluwa Adefeso ni ipinle Ogun ni orile ede Naijiria. O se ewe re ninu ayo ati idunnu. Awon obi re agba ni idile iya lo to o dagba pelu ife to wayami ati eko iwe to ye kooro, oun naa si dara po mo egbe akorin agbegbe ibe. Sugbon nnkan yi biri nigba ti o ko si wahala abe ile latari ijiya ti o n ri lati odo oko re. Inu laasigbo ijiya ara ati okan yii lo wa ti o fi padanu awon ibeji okunrin re mejeeji ti o bi ni kogbokogbo.Ninu odun 2019, omokunrin re, abisikeji, ti o figba kan je omo ogun oju omi ile Amerika naa tun pa ara re. Leyin eyi ni Adeola tun ri awon oro kobakungbe ti oko re ko nipa re si ori ero ayelujara ka de ibi pe oun loun fa iku omo awon ohun.Irora, ife, ati igbagbo Adeola fara han kedere ninu itan agbogbarimu yii ti o gbe kale ni ireti pe yoo de etigboo awon ti yoo wulo fun."e;Ninu iwe yii, Adeola gbe itan akikanju obinrin kan ti o doju ko wahala abele kale. Leyin-o-reyin, pelu iranlowo Olorun, o jawe olubori."e; Iloh, Friday Okechukwu (Ph. D)
Hallo! Ich bin Libroamiko, dein Buchberater.
Wie kann ich dir helfen?